Ki ni idajọ ti obinrin ba ri nnkan oṣu lẹyin wiwọle asiko irun? Njẹ o jẹ dandan fun un lati san an pada ti o ba ti mọ? Gẹgẹ bẹẹ naa ni ti o ba mọ ṣiwaju ki asiko irun tó lọ?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ki ni idajọ ti obinrin ba ri nnkan oṣu lẹyin wiwọle asiko irun? Njẹ o jẹ dandan fun un lati san an pada ti o ba ti mọ? Gẹgẹ bẹẹ naa ni ti o ba mọ ṣiwaju ki asiko irun tó lọ?
س31: ما الحكم إذا حاضت المرأة بعد دخول وقت الصلاة؟ وهل يجب عليها أن تقضيها إذا طهرت؟ وكذلك إذا طهرت قبل خروج وقت الصلاة؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Akọkọ: Ti obìnrin ba ri nǹkan oṣù lẹyin wiwọle asiko irun, o jẹ dandan fun un ti o ba mọ lati san irun ti o ri nǹkan oṣù rẹ ni àsìkò rẹ pada, ti ko ba i tíì ki i ṣiwaju ki o to ri nǹkan oṣù
Iyẹn ri bẹ́ẹ̀ fun ọ̀rọ̀ Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pe:
“Ẹni ti o ba ba ra'kah kan ninu irun ti ba irun”
Ti obinrin ba ba ninu akoko irun odiwọn rakah kan, ti o wa ri nnkan oṣu ṣiwaju ki o to kirun, ti o ba ti mọ́ra, sisan an pada maa jẹ dandan fun un
Ikeji: Ti o ba mọra kuro nibi nnkan oṣu ṣiwaju jijade akoko irun, sisan irun yẹn pada maa jẹ dandan fun un, ti o ba mọ́ ṣiwaju ki oòrùn to yọ pẹlu odiwọn rakah kan, sisan irun alufajari pada maa jẹ dandan fun un
Ti o ba mọ ṣiwaju wiwọ oòrùn pẹlu odiwọn rakah kan, sisan irun Asr pada maa di dandan fun un
Ti o ba mọ ṣiwaju idaji oru pẹlu odiwọn rakah kan, sisan irun Ishai jẹ dandan fun un,
Ti o ba mọ lẹyin idaji oru, irun Ishai ko jẹ dandan fun un, o maa ki irun alufajari ti asiko rẹ ba tó.
Ọlọhun- mimọ ni fun Un ti ọla Rẹ ga- sọ pe: {Nígbà tí ẹ bá sì fọkàn balẹ̀ (ìyẹn nígbà tí ẹ bá wọnú ìlú), kí ẹ kírun (ní pípé). Dájúdájú ìrun kíkí jẹ́ ọ̀ran-anyàn tí A fi àkókò sí fún àwọn onígbàgbọ́ òdodo}[Surah An-Nisâ': 103]
O n túmọ̀ si: Ọran-anyan kan ti a fi akoko kan pato si i, ko lẹtọọ fun ọmọniyan lati mu irun jade kuro ni akoko rẹ, tabi ki o bẹ̀rẹ̀ rẹ ṣiwaju akoko rẹ
ﺟ31: أولًا: المرأة إذا حاضت بعد دخول الوقت -أي: بعد دخول وقت الصلاة- فإنه يجب عليها إذا طهرت أن تقضي تلك الصلاة الّتي حاضت في وقتها، إذا لم تصلّها قبل أن يأتيها الحيض،
وذلك لقول الرسول ﷺ:
«مَنْ أَدْرَكَ رَكْعَةً مِنَ الصَّلَاةِ فَقَدْ أَدْرَكَ الصَّلَاةَ» [1]،
فإذا أدركت المرأة من وقت الصلاة مقدار ركعةٍ، ثم حاضت قبل أن تصلّي، فإنها إذا طهرت يلزمها القضاء.
[11] تقدم تخريجه.
ثانيًا: إذا طهرت من الحيض قبل خروج وقت الصلاة فإنه يجب عليها قضاء تلك الصلاة، فلو طهرت قبل أن تطلع الشمس بمقدار ركعةٍ وجب عليها قضاء صلاة الفجر،
ولو طهرت قبل غروب الشمس بمقدار ركعةٍ وجبت عليها صلاة العصر،
ولو طهرت قبل منتصف الليل بمقدار ركعةٍ وجب عليها قضاء صلاة العشاء،
فإن طهرت بعد منتصف الليل لم يجب عليها صلاة العشاء، وعليها أن تصلّي الفجر إذا جاء وقتها، قال الله سبحانه وتعالى:
﴿...فَإِذَا ٱطۡمَأۡنَنتُمۡ فَأَقِيمُواْ ٱلصَّلَوٰةَۚ إِنَّ ٱلصَّلَوٰةَ كَانَتۡ عَلَى ٱلۡمُؤۡمِنِينَ كِتَٰبٗا مَّوۡقُوتٗا﴾
[النساء:103]،
أي: فرضًا مؤقتًا بوقتٍ محدودٍ، لا يجوز للإنسان أن يخرج الصلاة عن وقتها، ولا أن يبدأ بها قبل وقتها.