السؤال
س۸: ما هي أعياد المسلمين؟
"Ibeere 7: Ki ni awọn ọdun awọn Musulumi?"
الجواب
ج:عيد الفطر وعيد الأضحى.
لما جاء في حديث أَنَسٍ رضي الله عنه، قَالَ:
قَدِمَ رَسُولُ اللَّهِ ﷺ الْمَدِينَةَ وَلَهُمْ يَوْمَانِ يَلْعَبُونَ فِيهِمَا، فَقَالَ: «مَا هَذَانِ الْيَوْمَانِ؟»، قَالُوا: كُنَّا نَلْعَبُ فِيهِمَا فِي الْجَاهِلِيَّةِ، فَقَالَ رَسُولُ اللَّهِ ﷺ:«إِنَّ اللَّهَ قَدْ أَبْدَلَكُمْ بِهِمَا خَيْرًا مِنْهُمَا: يَوْمَ الْأَضْحَى، وَيَوْمَ الْفِطْرِ»
رواه أبوداود.
وما سواهما من الأعياد فمن البدع.
"Idahun- Ọdun itunu aawẹ ati ọdun ileya."
"- Gẹgẹ bi o ṣe wa ninu hadīth Anas, o sọ pe: Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - wa si Medinah, wọn si ni ọjọ meji ti wọn fi maa n ṣere, o wa sọ pe: «Ki ni ọjọ mejeeji yii», wọn sọ pe: A maa n ṣere ninu ẹ ni igba aimọkan, Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - wa sọ pe:
"«Dajudaju Ọlọhun ti fi eyi ti o loore ju mejeeji lọ jirọ wọn fun yin: Ọjọ́ adhā (iléyá), ati ọjọ itunu aawẹ» "
"Abū Dāud ni o gba a wa."
"Eyi ti o ba si yatọ si mejeeji ninu awọn ọdun, ninu adadaalẹ ni."