Skip to content

السؤال

س۷: ما الواجب في النعم؟ وكيف تشكرها؟

Ibeere 6: Ki ni nnkan ti o jẹ dandan nibi awọn idẹra? Ati pe bawo ni waa ṣe dupẹ rẹ?

الجواب

ج- الواجب: شكرها؛ وذلك بالثناء على الله وحمده باللسان وأنه له الفضل وحده، واستعمال هذه النعم بما يرضي الله تَعَالَى، لا بمعصيته.

  • قال تعالى:

﴿فَٱذۡكُرُونِيٓ أَذۡكُرۡكُمۡ وَٱشۡكُرُواْ لِي وَلَا تَكۡفُرُونِ﴾

[البقرة: ١٥٢].

"Idahun- Nnkan ti o jẹ dandan ni: Didupẹ rẹ, iyẹn ni pẹlu yiyin Ọlọhun ati didu ọpẹ fun Un pẹlu ahọn ati pe Oun nikan ṣoṣo ni o ni ọla, ati lílo idẹra yii sibi nnkan ti yio yọ Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ninu, ti kii ṣe sibi ṣiṣẹ Ẹ."