"Ibeere ẹlẹẹkejidinlọgbọn: Ki ni o n jẹ ojo? Ki si ni o n jẹ igboya? "
- الباب / الفصل
- قسم الأخلاق
السؤال
س٢٨: ما هو الجبن؟ وما هي الشجاعة؟
"Ibeere ẹlẹẹkejidinlọgbọn: Ki ni o n jẹ ojo? Ki si ni o n jẹ igboya? "
الجواب
ج:الجبن: أن يخاف مما لا ينبغي أن يخاف منه.
مثل الخوف من قول الحق وإنكار المنكر.
الشجاعة: وهي الإقدام على الحق، وذلك مثل الإقدام في ساحات الجهاد للدفاع عن الإسلام والمسلمين.
- وكان النبي ﷺ في دعائه يقول:
«اللَّهُمَّ إنِّي أعوذُ بكَ من الجُبنِ...».
- وقال رسولُ اللهِ ﷺ:
«المؤمنُ القويُّ خيرٌ وأحبُّ إلى اللهِ مِن المؤمنِ الضَّعيفِ، وفي كُلٍّ خيرٌ»
رواه مسلم.
"Idahun- Al-Jubnu (Ojo): Ni ki o maa bẹru nkan ti ko tọ ki eeyan o bẹru."
"Gẹgẹ bíi pipaya sisọ ododo ati kikọ ibajẹ.
"Ash-Shajā‘ah (Akin): Oun naa ni gbigba iwaju nibi òdodo, iyẹn ni bii gbigba iwaju ni awọn ojude ija ẹsin lati da aabo bo Isilaamu ati awọn Musulumi."
"Ati pe Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - maa n sọ ninu adura rẹ pe:"
"«Allāhummọ innī a‘ūdhu biKa minal jubni...»."
"- Ojiṣẹ Ọlọhun -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "
"«Mu'mini to ni agbara loore, o si tun jẹ ẹniti Ọlọhun nífẹ̀ẹ́ si ju Mu'mini to jẹ ọlẹ lọ, ati pe oore n bẹ lara ọkọọkan wọn."
Muslim ni o gba a wa.