Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹketadinlọgbọn: Ki ni o n jẹ ina-apa? Ki si ni o n jẹ ahun? Ki ni o n jẹ ọrẹ?"

الباب / الفصل
قسم الأخلاق

السؤال

س٢٧: ما هو الإسراف؟ وما هو البخل؟ وما هو الكرم؟

"Ibeere ẹlẹẹketadinlọgbọn: Ki ni o n jẹ ina-apa? Ki si ni o n jẹ ahun? Ki ni o n jẹ ọrẹ?"

الجواب

ج:الإسراف: هو إنفاق المال بغير حقه، وعكسه: البخل: وهو الإمساك عن حقه.

والصحيح هو الوسط بينهما، وأن يكون المسلم كريمًا.

  • قال تَعَالَى:

﴿وَٱلَّذِينَ إِذَآ أَنفَقُواْ لَمۡ يُسۡرِفُواْ وَلَمۡ يَقۡتُرُواْ وَكَانَ بَيۡنَ ذَٰلِكَ قَوَامٗا﴾

[الفرقان: ٦٧].

"Idahun- ina-apa: Oun ni nina owo ni ọna ti ko lẹtọọ,"

Idakeji ẹ: Ahun: Oun ni ki eeyan ma ṣe ẹtọ rẹ fun un.

"Eyi to tọ ni wiwa laarin mejeeji, ki musulumi si jẹ ọlọrẹ.

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Àwọn tí ó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n bá náwó, wọn kò ná ìná-àpà, wọn kò sì ṣahun; (ìnáwó wọn) wà láààrin ìyẹn ní ìwọ̀ntún-wọ̀nsì 67}. "

[Suuratul-Furqan: 63].