Skip to content

السؤال

س١٣: ما أنواع خُلق الحياء؟

"Ibeere ẹlẹẹkẹtala: Ki ni awọn iran iwa itiju? "

الجواب

ج:١. الحياء من الله: يكون بأن لا تعصيه سُبْحَانَهُ.

  1. الحياء من الناس: ومن ذلك ترك الكلام الفاحش البذيء وكشف العورة.
  • قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:

«الإِيمانُ بِضْعٌ وسَبعونَ» - أو: «بِضْعٌ وسِتُّونَ» - «شُعْبةً، أَعْلَاها: قَوْلُ: لا إِلَهَ إلَّا اللهُ. وأَدْناها: إِماطةُ الأَذَى عنِ الطَّريقِ. والحَياءُ شُعْبةٌ مِنَ الإِيمانِ»

رواه مسلم.

"Idahun- 1- Ìtìjú Ọlọhun: Yoo maa wáyé pẹ̀lú pe ki o ma maa ṣẹ Ẹ -mimọ ni fun Un-. "

"2- Itiju awọn eniyan: Nínú iyẹn ni gbigbe ọrọ buruku ti ko dara ju silẹ ati ṣiṣi ihoho silẹ. "

"Ojiṣẹ Ọlọhun -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "

Igbagbọ ni ẹka aadọrin ati diẹ tabi ọgọta ati diẹ, eyi to ga julọ nibẹ ni gbólóhùn: Laa ilaaha illallohu. Eyi to kere julọ nibẹ: Mímú suta kuro ni oju-ọna,ati pe itiju jẹ ẹka kan ninu igbagbọ”.

Muslim ni o gba a wa.