Skip to content

السؤال

س١١: ما ضد الصبر؟

"Ibeere ẹlẹẹkọkanla: Ki ni idakeji suuru? "

الجواب

ج:- وهو عدم الصبر على الطاعة، وعدم الصبر عن المعصية، والتسخط على الأقدار بالقول أو الفعل.

من صوره:

  • تَمنِّي الموتِ.
  • قَالَ النَّبِيُّ صَلَّى اللَّهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ:

«لَا يَتَمَنَّيَنَّ أَحَدُكُمُ الْمَوْتَ مِنْ ضُرٍّ أَصَابَهُ، فَإِنْ كَانَ لَا بُدَّ فَاعِلًا فَلْيَقُلِ: اللَّهُمَّ أَحْيِنِي مَا كَانَتِ الْحَيَاةُ خَيْرًا لِي، وَتَوَفَّنِي إِذَا كَانَتِ الْوَفَاةُ خَيْرًا لِي»

متفق عليه.

  • ضرْبُ الخُدودِ.
  • شَقُّ الثِّيابِ.
  • نَشْرُ الشُّعورِ.
  • الدُّعاءُ على النفس بالهلاك.
  • قال عليه الصلاة والسلام:

«لَيْسَ مِنَّا مَنْ لَطَمَ الْخُدُودَ، وَشَقَّ الْجُيُوبَ، وَدَعَا بِدَعْوَى الْجَاهِلِيَّةِ»

رواه البخاري.

  • قال النبي عَلَيْهِ الصَّلَاةُ وَالسَّلَامُ:

«إِنَّ عِظَمَ الْجَزَاءِ مَعَ عِظَمِ الْبَلَاءِ وَإِنَّ اللَّهَ إِذَا أَحَبَّ قَوْمًا ابْتَلَاهُمْ، فَمَنْ رَضِيَ فَلَهُ الرضا، وَمَنْ سَخِطَ فَلَهُ السَّخَطُ»

رواه الترمذي وابن ماجة.

"Idahun- Oun ni aiṣe suuru lori itẹle, ati aiṣe suuru kuro nibi ẹṣẹ, ati aiyọnu si awọn kádàrá Ọlọhun pẹlu ọrọ ati iṣẹ. "

"Ninu awọn aworan ẹ ni:

"Imaa tanmọọn iku."

"Imaa gba ara ẹni ni oju."

"Imaa fa aṣọ ya."

"Imaa tu irun ka si ori (latari fifi ibanujẹ hàn)."

"Imaa ṣe adua iparun lori ara ẹni."

"Anabi -ki ikẹ ati ọla maa ba a- sọ pe:"

"Ẹsan n bẹ pẹlu titobi adanwo, ati pe dajudaju ti Ọlọhun ba nífẹ̀ẹ́ ijọ kan yio dan wọn wo, ẹniti o ba yọnu, iyọnu o maa jẹ tiẹ, ẹniti o ba si binu, ibinu o maa jẹ tiẹ."

"Tirmidhiy ati Ibnu Mājah ni wọn gba a wa."