"Ibeere kẹsan-an: Ki ni idakeji ododo? "
- الباب / الفصل
- قسم الأخلاق
السؤال
س٩: ما ضد الصدق؟
"Ibeere kẹsan-an: Ki ni idakeji ododo? "
الجواب
ج:الكذب، وهو خلاف الحقيقة، من ذلك، الكذب على الناس، وإخلاف المواعيد، وشهادة الزور.
- قال النبي صلى الله عليه وسلم:
«وإنَّ الكذِبَ يَهْدي إلى الفُجورِ، وإنَّ الفُجورَ يَهْدي إلى النَّارِ، وإنَّ الرَّجلَ لَيَكذِبُ حتَّى يُكتَبَ عندَ اللهِ كذَّابًا»
متفق عليه.
- وقال النبي عَلَيْهِ الصَّلَاةُ وَالسَّلَامُ:
«آيةُ المُنافِقِ ثَلاثٌ» -وذكر منها- «إذا حدَّثَ كَذَبَ، وإذا وَعَدَ أَخلَفَ»
"Idahun- Irọ, òun ni idakeji ododo, ninu iyẹn ni, pipa irọ mọ awọn eniyan, ati yiyapa awọn adehun, ati jijẹrii eke. "
"Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe:
“Ati pe dajudaju irọ maa n tọ ni sọna sibi iwa aburu, dajudaju iwa aburu maa n tọ ni sọna sinu ina, ati pe dajudaju eniyan a maa pa irọ titi ti o fi maa di onirọ lọdọ Ọlọhun”.
Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa.
Ati pe Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "
“Àmì ṣọbẹ-ṣelu musulumi, mẹta ni” -o darukọ ninu ẹ- “Ti o ba sọrọ, yoo pa irọ, ti o ba ṣe adehun yóò yapa”.