Skip to content

السؤال

س٢٦: ما هو التجسس؟

Ibeere ẹlẹẹkẹrindinlọgbọn: Ki ni o n jẹ itọpinpin? "

الجواب

ج:هو الكشف والبحث عن عورات الناس وما يسترونه.

من صوره المحرمة:

  • الاطلاع على عورات الناس في البيوت.
  • استماع المرء إلى حديث قوم بدون علمهم.
  • قال تَعَالَى:

﴿وَلَا تَجَسَّسُوا ...﴾

[الحجرات: ١٢].

"Idahun- Oun ni afihan ati iwadii nipa awọn ihoho awọn eniyan ati nnkan ti wọn n bo. "

"Ninu awọn aworan ẹ ti a ṣe ni eewọ ni: "

Wíwo ihoho awọn eniyan ninu awọn ile wọn." Ki eniyan maa tẹti gbọ ọrọ awọn ijọ kan ti wọn ko si mọ̀ si i.

Ki eniyan maa tẹti gbọ ọrọ awọn ijọ kan ti wọn ko si mọ̀ si i.

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Ẹ má ṣe tọpinpin ara yín...}."

[Suuratul-Hujuraat 11].