Skip to content

السؤال

س٨: ما هو خلق الصدق؟

"Ibeere 8: Ki ni o n jẹ iwa ododo?"

الجواب

ج:هو الإخبار بما يطابق الواقع أو الشيء على ما هو عليه.

ومن صوره:

  • الصدق في الحديث مع الناس.
  • الصدق في الوعد.
  • الصدق في كل قول وعمل.
  • قال النبي عَلَيْهِ الصَّلَاةُ وَالسَّلَامُ:

«إنَّ الصِّدقَ يَهْدي إلى البِرِّ، وإنَّ البِرَّ يَهْدي إلى الجنَّةِ، وإنَّ الرَّجلَ لَيَصْدُقُ حتَّى يكونَ صِدِّيقًا»

متفق عليه.

"Idahun- Oun ni ifunni ni iro pẹlu nnkan ti yio ba nnkan ti o n ṣẹlẹ mu tabi nipa nkan gẹgẹ bi o ṣe wa."

"Ati pe ninu awọn aworan rẹ ni:

"Sisọ ododo nibi isọrọ pẹlu awọn eniyan."

"Sisọ ododo nibi adehun."

"Sisọ ododo nibi gbogbo ọrọ ati iṣe. "

"Anabi -ki ikẹ ati ọla maa ba a- sọ pe:"

“Dajudaju ododo maa n tọ ni sọna sibi dáadáa, ati pe dajudaju dáadáa maa n tọ ni sọna sinu alujanna, ati pe dajudaju eniyan a maa sọ ododo titi ti o fi maa di olódodo”

Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa.