وهذهِ رِسالَةٌ مُوجَزَةٌ لَكَ يا مَن فَقَدتَ قَرِيبًا أو عَزِيزًا، أو حَبِيبًا، نَسألُ اللَّهَ عزَّ وجلَّ أن ينفعنا وإياكَ بِها، وهي بِعنوان: (أحكامُ الجَنائِز).
Pelu oruko Olohun Oba Ajoke aye Oba Asake orun. Al-Wajiiz Ìlànà ẹkọ ti yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́ fun Musulumi tuntun Pelu oruko Olohun Oba Ajoke aye Oba Asake orun. Ọrọ isiwaju Gbogbo ọpẹ jẹ ti Ọlọhun ti O fi ọna mọ wa fun Isilaamu, ti O tọ wa si awọn ọna ọla, ti O gbe ẹni ti o daa julọ ninu awọn eniyan dide ninu wa, - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-. Lẹyin naa: O n dun mọ wa ninu lati ti eto ẹkọ yii si iwaju rẹ ti o maa sọ nipa ẹsin ododo (Ẹsin Isilaamu), ti o si maa ṣe alaye awọn nnkan ti o jẹ dandan lati mọ àti láti ṣe, lati le jẹ kọkọrọ fun ẹ lati da ẹsin rẹ mọ, ki o le jẹ olukunlọwọ fun ẹ lori…
Islaamu ni ijuwọ-jusẹ silẹ fun Ọlọhun, Oluṣẹda ati Oludari gbogbo agbaye, ati itẹriba fun Un ni ti ifẹ ati gbigbetobi, ipilẹ Islaamu ni níní igbagbọ si Ọlọhun, ati pe Oun ni Ọba Asẹ́dàá, bẹẹ si ni ẹda ni gbogbo ohun tó yatọ Sii, ati pé Òun nikan ṣoṣo ni o tọ láti jọsin fún, ko si orogun fun Un, bẹ ni ko si ẹnikan ti a gbọdọ jọsin fun lododo ayafi Oun nikan, ti Rẹ̀ ni awọn orukọ tó rẹwa julọ ati awọn iroyin tó ga julọ, Oun ni O ni pipe laisi abuku, kò bimọ, ẹnikan ò si bi, bẹẹni ko si iru tabi alafijọ fun Un, ko si ki n ko si ara nkankan ninu awọn ẹda Rẹ̀. Ati pé Islaamu ni ẹsin Ọlọhun Ọba…
Bí Anabi - kí ikẹ àti ọla Ọlọ́hun máa bá a - ṣe n kirun.
79 èdè
Bí Anabi - kí ikẹ àti ọla Ọlọ́hun máa bá a - ṣe n kirun.
Ìwé 'Kayfiyyatu ṣalātin Nabiyy ﷺ ( Bí anọbi ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ máa bá ) ni Ọlọla wa Olumọ agba Abdul Azeez ọmọ Bāz - ki Ọlọhun kẹ ẹ - tí ko àsàyàn ọrọ ṣe lórí irun Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a -, sínú rẹ, pẹ̀lú ọ̀nà ìgbékalẹ̀ tí ó rọrùn àti ìlànà tí ó péye, tí ó ní ìpìlẹ̀ nínú àwọn ìpìlẹ ọrọ tí ó jẹ́ ododo, láti jẹ́ amọ̀nà fún Musulumi nínú irun rẹ̀. Ó sì ti ṣàlàyé àwọn òpó irun kíkí, àwọn Sunna rẹ̀, àti àwọn ìrísí rẹ̀ nínú rẹ̀, bẹ̀rẹ̀ láti orí alùwàlá títí dé orí Tasliim ( pipari irun pẹlu salaman , nígbàtí ó pa ẹ̀rí pọ̀ mọ́ àlàyé, tí ó n pèpè sí títẹ̀lé Anabi - ki ikẹ ati ọla…