A wa ni ọdọ ‘Umar, o wa sọ pe: «Wọn kọ fun wa kuro nibi ifipaṣe-nnkan»
Lati ọdọ Anas – ki Ọlọhun yọnu si i – o sọ pe:
A wa ni ọdọ ‘Umar, o wa sọ pe: «Wọn kọ fun wa kuro nibi ifipaṣe-nnkan»
كُنَّا عِنْدَ عُمَرَ فَقَالَ: «نُهِينَا عَنِ التَّكَلُّفِ».
‘Umar – ki Ọlọhun yọnu si i– n sọ wipe dajudaju Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – kọ fun wọn kuro nibi imaa ṣe nkan ti ìnira wa nibẹ lai ni bukaata si i, yala o jẹ ọrọ ni abi iṣe.
...:
Ninu ifipaṣe-nnkan ti wọn kọ ni: Apọju ibeere, tabi ki o la nkan ti ko ni imọ nipa rẹ bo ara rẹ lọrun, tabi ki o le nibi alamọri ti Ọlọhun fi igbalaaye si i.
O tọ fun Musulumi ki o jẹ ki ẹ̀lẹ̀ mọ́ òun lára, ati ki o má maa fi agídí sọ̀rọ̀ tabi ṣiṣẹ́: Nibi jíjẹ rẹ, ati mimu rẹ, ati awọn ọrọ rẹ, ati gbogbo ìṣesí rẹ.
Isilaamu ẹsin irọrun ni.
Tira Sọhiihu ti Bukhaariy (9/ 95) (7293).
Àlékún (10)
نزهة المتقين.
لمصطفى الخن وغيره (2/ 1136).
شرح رياض الصالحين.
لابن عثيمين (6/ 391).
فتح الباري شرح صحيح البخاري.
لابن حجر (13/ 270).
النهاية في غريب الحديث والأثر.
لابن الأثير (4/ 196).
تطريز رياض الصالحين.
لفيصل آل مبارك (ص930).