Skip to content

Ti nǹkan oṣù obìnrin bá jẹ ọjọ mẹjọ tabi ọjọ meje, lẹyin naa o wa tẹsiwaju pẹlu rẹ ni ẹẹkan tabi ẹẹmeji tabi ju iyẹn lọ, ki ni idajọ naa?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Ti nǹkan oṣù obìnrin bá jẹ ọjọ mẹjọ tabi ọjọ meje, lẹyin naa o wa tẹsiwaju pẹlu rẹ ni ẹẹkan tabi ẹẹmeji tabi ju iyẹn lọ, ki ni idajọ naa?

س4: إذا كانت المرأة عادتها الشهرية ثمانية أيامٍ أو سبعة أيامٍ، ثم استمرت معها مرةً أو مرتين أكثر من ذلك، فما الحكم؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Ti nǹkan oṣù obinrin yii ba jẹ ọjọ mẹfa tabi meje, lẹyin naa ti akoko yii wá gùn síi, ti o wa di ọjọ mẹjọ tabi mẹsan-an tabi mẹwaa tabi mọ́kànlá, ko nii kirun titi yoo fi mọ

Ìyẹn rí bẹ́ẹ̀; nitori pe Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ko pa aala kan pato nibi ẹjẹ nnkan oṣu,

Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga sọ pe-: {Wọ́n sì ń bi ọ́ léèrè nípa n̄ǹkan oṣù (obìnrin). Sọ pé: “Ìnira ni (sísúnmọ́ wọn lásìkò náà)}[Surah Al-Baqarah: 222]

Gbogbo igba ti ẹjẹ yii ba n ṣẹku, obinrin naa maa wa lori iṣesi rẹ titi yoo fi mọ, ti yoo wẹ, lẹyin naa yoo kirun, ti o ba yọ si i ni oṣu keji ti o din si iyẹn, yoo wẹ ti o ba ti mọ, koda ki o ma jẹ lori akoko ti o ṣiwaju

Nnkan ti o ṣe koko ni pe dajudaju obinrin gbogbo igba ti ẹjẹ nnkan oṣu ba ti n bẹ pẹlu rẹ, ko nii kirun, boya ẹjẹ nnkan oṣu naa papọ mọ àṣà rẹ ti o ṣiwaju, tabi o lekun si i, tabi o din, ti o ba ti mọ yoo kirun

ﺟ4: إذا كانت عادة هذه المرأة ستة أيامٍ أو سبعةً، ثم طالت هذه المدة، وصارت ثمانيةً أو تسعةً أو عشرةً أو أحد عشر يومًا فإنها تبقى لا تصلّي حتى تطهر،

وذلك لأن النبي ﷺ لم يحد حدًّا معيّنًا في الحيض، وقد قال الله تعالى:

﴿وَيَسۡـَٔلُونَكَ عَنِ ٱلۡمَحِيضِۖ قُلۡ هُوَ أَذٗى...﴾

[البقرة:222]،

فمتى كان هذا الدم باقيًا فإن المرأة على حالها حتى تطهر، وتغتسل، ثم تصلّي، فإذا جاءها في الشهر الثاني ناقصًا عن ذلك فإنها تغتسل إذا طهرت وإن لم يكن على المدة السابقة.

والمهمّ أن المرأة متى كان الحيض معها موجودًا فإنها لا تصلّي، سواءٌ كان الحيض موافقًا للعادة السابقة، أو زائدًا عنها، أو ناقصًا، وإذا طهرت تصلّي.