Ti ẹjẹ kékeré díẹ̀ ba jade lati ara obinrin ni ọsan Ramadan, ti ẹjẹ yii wa tẹsiwaju pẹlu rẹ fun gbogbo oṣu Ramadan ti o si n gba awẹ, njẹ awẹ rẹ ni alaafia?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ti ẹjẹ kékeré díẹ̀ ba jade lati ara obinrin ni ọsan Ramadan, ti ẹjẹ yii wa tẹsiwaju pẹlu rẹ fun gbogbo oṣu Ramadan ti o si n gba awẹ, njẹ awẹ rẹ ni alaafia?
س6: إذا نزل من المرأة في نهار رمضان نقط دمٍ يسيرةٌ، واستمر معها هذا الدم طوال شهر رمضان وهي تصوم، فهل صومها صحيحٌ؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Bẹẹni, awẹ rẹ ni alaafia, ṣugbọn awọn ẹ̀kán ẹ̀jẹ̀ yii ko jẹ nnkankan; nitori pe o n jade lati inu awọn iṣan, wọn gba ọrọ wa lati ọdọ Aliy ọmọ Abu Talib- ki Ọlọhun yọnu si i- pe o sọ pe: Dajudaju awọn ẹ̀kán ẹ̀jẹ̀ ti o da gẹgẹ bii àmúrun yii, kii ṣe ẹjẹ nnkan oṣu. Báyìí ni wọn ṣe sọ nipa rẹ (ki Ọlọhun yọnu si i).
ﺟ6: نعم، صومها صحيحٌ، وأما هذه النّقط فليست بشيءٍ؛ لأنها من العروق، وقد أثر عن عليّ بن أبي طالبٍ رضي الله عنه أنه قال: إن هذه النّقط التي تكون كرعاف الأنف ليست بحيضٍ، هكذا يذكر عنه رضي الله عنه.