"Ibeere ẹlẹẹkẹtala: Parí hadiisi: “Ninu didara Isilaamu ọmọniyan...”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ?"
- الباب / الفصل
- قسم الحديث
السؤال
س13: أكمل حديث «من حسن إسلام المرء ...»، واذكر بعض فوائده.
"Ibeere ẹlẹẹkẹtala: Parí hadiisi: “Ninu didara Isilaamu ọmọniyan...”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ?"
الجواب
ج:عن أبي هريرة رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ قال: قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:
«من حسن إسلام المرء: تركُه ما لا يعنيه»
رواه الترمذي وغيره.
من فوائد الحديث:
- ترك ما لا يعني الإنسان من أمور دين غيره ودنياه.
- أن ترك ما لا يعني من كمال إسلامه.
"Idahun- lati ọdọ Abu Hurayra- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Ojisẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "
“Ninu dida Isilaamu ọmọniyan: Ni ki o maa gbe nnkan ti ko ba kan an ju silẹ”.
"Tirmidhi ati ẹni ti o yatọ si i ni wọn gba a wa.
"Ninu awọn anfaani to wa ninu Hadiisi naa: "
"1- Gbigbe nnkan ti ko ba kan eniyan ju silẹ ninu awọn alamọri ẹsin ẹlomiran ati aye rẹ. "
"2- Ki o gbe nnkan ti ko kan an ju silẹ wa ninu pipe ẹsin rẹ. "