"Ibeere ẹlẹẹkẹrinla: Parí hadiisi: “Ẹni ti o ba ka arafi kan ninu iwe Ọlọhun…”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ? "
- الباب / الفصل
- قسم الحديث
السؤال
س١٤: أكمل حديث: «من قرأ حرفًا من كتاب الله...»، واذكر بعض فوائده.
"Ibeere ẹlẹẹkẹrinla: Parí hadiisi: “Ẹni ti o ba ka arafi kan ninu iwe Ọlọhun…”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ? "
الجواب
ج:عن عبدِ الله بن مسعودٍ رضي الله عنه: أنَّ النبي صلى الله عليه وسلم، قال:
«مَن قرأ حرفًا من كتاب الله فله به حسنة، والحسنة بعشر أمثالها، لا أقول: ألف لام ميم حرف، وَلَكِنْ ألفٌ حرفٌ، ولامٌ حرفٌ، وميمٌ حرفٌ»
رواه الترمذي.
بعض فوائد الحديث:
- فضل تلاوة القرآن.
- وأن بكل حرف تقرؤه لك به حسنات.
*******
"Idahun- lati ọdọ Abdulahi ọmọ Mas'ud: Pe Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "
“Ẹni ti o ba ka arafi kan ninu iwe Ọlọhun yio gba dáadáa kan pẹlu ẹ, ati pe dáadáa jẹ ilọpo mẹ́wàá iru ẹ, mi ko sọ pe: Alif Lam Mim jẹ arafi kan, bi ko ṣe pe Alif jẹ arafi kan, Lam jẹ arafi kan, Mim jẹ arafi kan”.
Tirmidhiy ni o gba a wa
Anfaani ti a maa ṣe lara Hadiisi naa ni pe
"1- Ọla ti n bẹ fun kika Kuraani."
- Dáadáa o maa wa fun ẹ fun gbogbo arafi kọọkan ti o n ka. "