Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹfa: Ki ni itumọ jijẹrii pe dajudaju Muhammad ni Ojiṣẹ Ọlọhun? "

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

"Ibeere ẹlẹẹkẹfa: Ki ni itumọ jijẹrii pe dajudaju Muhammad ni Ojiṣẹ Ọlọhun? "

س6: ما معنى شهادة أنَّ محمدًا رسول الله؟

الجواب

"Idahun- Itumọ ẹ ni pe: Ọlọhun ni O ran an si gbogbo aye ni olufunni ni iro ìdùnnú ati olukilọ "

"O si jẹ dandan: "

"Titẹle e nibi nnkan to ba pa laṣẹ. "

"Gbigba a lododo nibi nnkan ti o ba sọ. "

"Ki a ma ṣẹ ẹ. "

"Ki a ma jọsin fun Ọlọhun afi pẹlu nnkan ti O ṣe lofin, oun ni itẹle oju-ọna ojiṣẹ Ọlọhun ati gbigbe adadaalẹ ju silẹ. "

"Ọba -ti ọla Rẹ ga- sọ pe-: {Ẹnikẹ́ni t’ó bá tẹ̀lé Òjíṣẹ́ náà, ó ti tẹ̀lé (àṣẹ) Allāhu...} [Suuratun Nisâ': 80], O tun sọ- mimọ ni fun Un- pe:

{Àti pé kò níí sọ̀rọ̀ ìfẹ́-inú 3 Kò níí sọ ohun kan tayọ ìmísí tí A fi ránṣẹ́ sí i 4}

"[Suuratun Najm: 3, 4]

"Ọba - ti O lágbára ti O gbọnngbọn - sọ pe: "

"{Dájúdájú àwòkọ́ṣe rere wà fun yín lára Òjíṣẹ́ Allāhu fún ẹnikẹ́ni tí ó bá ń retí (ẹ̀san) Allāhu àti Ọjọ́ Ìkẹ́yìn, tí ó sì rántí Allāhu ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ (ìgbà) 21}

[Surah Al-Ahzâb: 21]"

ج:معناها: أن الله أرسله للعالمين بشيرًا ونذيرًا.

  • ويجب:
  1. طاعته فيما أمر.
  2. تصديقه فيما أخبر.
  3. عدم معصيته.
  4. لا يعبد الله إلا بما شرع، وهو الاقتداء بالسنة وترك البدعة.

قال تَعَالَى:

﴿مَّن يُطِعِ ٱلرَّسُولَ فَقَدۡ أَطَاعَ ٱللَّهَۖ﴾

[النساء: 80]،

وقال سُبْحَانَهُ:

﴿وَمَا يَنطِقُ عَنِ ٱلۡهَوَىٰٓ 3

إِنۡ هُوَ إِلَّا وَحۡيٞ يُوحَىٰ 4﴾

[النجم: 3-4].

وقال جَلَّ وَعَلَا:

﴿لَّقَدۡ كَانَ لَكُمۡ فِي رَسُولِ ٱللَّهِ أُسۡوَةٌ حَسَنَةٞ لِّمَن كَانَ يَرۡجُواْ ٱللَّهَ وَٱلۡيَوۡمَ ٱلۡأٓخِرَ وَذَكَرَ ٱللَّهَ كَثِيرٗا﴾

[الأحزاب: 21].