Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹjọ: Kí ni o n jẹ ijọsin? "

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

"Ibeere ẹlẹẹkẹjọ: Kí ni o n jẹ ijọsin? "

س٨: ما هي العبادة؟

الجواب

"Idahun- Oun ni orukọ kan to ko gbogbo nnkan ti Ọlọhun nífẹ̀ẹ́ rẹ ati nnkan ti O yọnu si sínú nínú awọn ọrọ ati iṣẹ ti o pamọ ati èyí tí o han."

"Eyi to han: Gẹgẹ bii iranti Ọlọhun pẹlu ahọn bii iṣe afọmọ, ati idupẹ, ati igbe Ọlọhun tobi, ati kiki irun ati ṣiṣe Hajj. "

"Eyi to pamọ: Gẹgẹ bii igbarale Ọlọhun ati ibẹru ati agbiyele. "

ج:هي اسمٌ جامعٌ لكلِّ ما يحبُّه الله ويرضاه من الأقوال والأعمالِ الباطنةِ والظاهرةِ.

  • الظاهرة: مثل ذكر الله باللسان من التسبيح والتحميد والتكبير، والصلاة والحج.
  • الباطنة: مثل التوكل والخوف والرجاء.