Ki ni awọn ìran ifọkantan ati awọn aworan rẹ?"
- الباب / الفصل
- قسم الأخلاق
السؤال
س٦: ما أنواع الأمانة وصورها؟
"Ibeere 6: Ki ni awọn ìran ifọkantan ati awọn aworan rẹ?"
الجواب
ج:١. أمانة في حفظ حقوق الله تَعَالَى.
صورها: الأمانة في أداء العبادات من الصلاة، والزكاة، والصيام، والحج، وغيرها مما افترض الله علينا.
- أمانة في حفظ حقوق الخلق:
- من حفظ أعراض الناس.
- وأموالهم.
- ودمائهم.
- وأسرارهم، وجميع ما ائتمنك عليه الناس.
قال تَعَالَى في ذِكر صِفات المفلحين:
﴿وَٱلَّذِينَ هُمۡ لِأَمَٰنَٰتِهِمۡ وَعَهۡدِهِمۡ رَٰعُونَ﴾
[المؤمنون: ٨].
"Idahun- "
"1- Ifọkantan nibi sisọ awọn iwọ̀ Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga-."
"Awọn aworan rẹ: Ifọkantan nibi pipe awọn ijọsin bi Irun, ati Zakah, ati Aawẹ, ati Hajj, ati eyi ti o yatọ si wọn ninu awọn nnkan ti Ọlọhun ṣe ni ọranyan le wọn lori."
"Ifọkantan nibi sisọ awọn iwọ awọn ẹda:"
"Nibi sisọ ijẹ-ọmọluabi awọn eeyan."
"Ati awọn dukia wọn."
"Ati awọn ẹjẹ wọn."
"Ati awọn kọkọ wọn, ati gbogbo nnkan ti awọn eeyan ba fi ọkan balẹ si ọ lọdọ lori rẹ."
"Ọba- ti ọla Rẹ ga- sọ nibi awọn iroyin awọn olujere pe:"
"{àwọn t’ó ń ṣọ́ àgbàfipamọ́ wọn àti àdéhùn wọn 8}"
"[Surah Al-Mu’minûn: 1, 2]"