Skip to content

السؤال

س٥: ما ضد الإحسان؟

"Ibeere karun-un: Ki ni idakeji ṣiṣe dáadáa? "

الجواب

ج:ضد الإحسان الإساءة.

  • ومن ذلك: ترك الإخلاص في عبادة الله تَعَالَى.
  • وعقوق الوالدين.
  • وقطع الأرحام.
  • وسوء الجوار.
  • وترك الإحسان إلى الفقراء والمساكين وغير ذلك من سيء الأقوال والأعمال.

"Idahun- Idakeji ṣiṣe dáadáa ni ṣíṣe aida. "

*Ninu iyẹn ni: Gbígbé imọkanga ju silẹ nibi ijọsin fun Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga-

"Ṣiṣẹ obi mejeeji "

Gige okun ebi.

Aladugboo buruku

"*Ati gbigbe ṣiṣe daadaa si awọn talaka ati alaini ju silẹ, ati eyi ti o yatọ si iyẹn ninu awọn ọrọ ati iṣẹ buruku."