Ki ni wọn n pe ni ibẹru? Ki ni wọn n pe ni agbiyele? Ki si ni ẹri?
- الباب / الفصل
- قسم العقيدة
السؤال
س31: ما هو الخوف؟ وما هو الرجاء؟ وما الدليل؟
Ki ni wọn n pe ni ibẹru? Ki ni wọn n pe ni agbiyele? Ki si ni ẹri?
الجواب
ج:الخوف: هو الخشية من الله ومن عقابه.
الرجاء: هو الطمع في ثواب الله ومغفرته ورحمته.
الدليل: قوله تَعَالَى:
﴿أُوْلَٰٓئِكَ ٱلَّذِينَ يَدۡعُونَ يَبۡتَغُونَ إِلَىٰ رَبِّهِمُ ٱلۡوَسِيلَةَ أَيُّهُمۡ أَقۡرَبُ وَيَرۡجُونَ رَحۡمَتَهُۥ وَيَخَافُونَ عَذَابَهُۥٓۚ إِنَّ عَذَابَ رَبِّكَ كَانَ مَحۡذُورٗا﴾
[الإسراء: 57].
وقال تَعَالَى:
﴿نَبِّئْ عِبَادِي أَنِّي أَنَا الْغَفُورُ الرَّحِيمُ 49 وَأَنَّ عَذَابِي هُوَ الْعَذَابُ الْأَلِيمُ 50﴾
[الحجر: 49-50]
Ibẹru: Oun ni bibẹru Ọlọhun ati iya Rẹ.
Ṣíṣe agbiyele: Oun ni ṣiṣe agbiyele ẹsan lọdọ Ọlọhun ati aforijin Rẹ ati ikẹ Rẹ.
Ẹri: Ọ̀rọ̀ Ọlọhun Ọba ti O ga:
Àwọn wọ̀nyẹn tí wọ́n ń pè (lẹ́yìn Rẹ̀) ń wá àtẹ̀gùn sọ́dọ̀ Olúwa wọn ni! - Èwo nínú wọn l’ó súnmọ́ (Allāhu) jùlọ (báyìí)? – Àwọn náà ń retí ìkẹ́ Allāhu, wọ́n sì ń páyà ìyà Rẹ̀. Dájúdájú ìyà Olúwa rẹ jẹ́ ohun tí wọ́n gbọ́dọ̀ ṣọ́ra fún. 57
[Suuratul-Israa: 57].
Allah tun sọ pe:
Fún àwọn ẹrúsìn Mi ní ìró pé dájúdájú Èmi ni Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run. 49 Àti pé dájúdájú ìyà Mi ni ìyà ẹlẹ́ta-eléro 50
[Suuratul-Hijr: 49, 50].