Ibeere ẹlẹẹkẹtalelọgbọn: Ṣe alaye awọn orukọ yii?
- الموضوعات
- الإيمانالإيمان بالله تعالى
- التصنيف الشرعي
- العقيدةالإيمان بالله عز وجلتوحيد الأسماء والصفات
- الباب / الفصل
- قسم العقيدة
السؤال
س33: اشرح هذه الأسماء.
Ibeere ẹlẹẹkẹtalelọgbọn: Ṣe alaye awọn orukọ yii?
الجواب
ج:الله: ومعناه الإله المعبود بحق، وحده لا شريك له.
- الرب: أي الخالق والمالك الرازق والمدبر وحده سُبْحَانَهُ.
- السميع: الذي وسع سمعه كل شيء، ويسمع كل الأصوات على اختلافها وتنوعها.
- البصير: الذي يرى كل شيء، ويبصر كل شيء صغر أو كبر.
- العليم: فهو الذي أحاط علمه بكل شيء بالماضي والحاضر والمستقبل.
- الرحمن: الذي وسعت رحمته كل مخلوق وحي، فكل العباد والمخلوقات تحت رحمته.
- الرزاق: الذي عليه رزق جميع المخلوقات من الإنس والجن وجميع الدواب.
- الحي: الحي الذي لا يموت، وكل الخلق يموتون.
- العظيم: الذي له الكمال كله والعظمة كلها في أسمائه وصفاته وأفعاله.
- الحكيم: الذي أحكم خلقه، وأتقنه، وأحسنه، وله الحكمة في خلقه وأمره.
- والحكمة: وضع الأشياء مواضعها، وتنزيلها منازلها.
Idahun- ALLAAHU: Ìtumọ̀ rẹ ni pe Ọba ti a n sin pẹ̀lú ododo, Oun nikan ni O da wa ti ko si ni akẹgbẹ.
AR-ROBB: Ìtumọ̀ rẹ ni Oludẹdaa, Olukapa, Olupese, Oluṣeto ni Oun nikan ṣoṣo, mimọ fun Un.
AS-SAMIIHU: Ẹni tí igbọran Rẹ kari gbogbo nnkan, O si n gbọ gbogbo ohun tòun ti bi o ṣe pe oríṣiríṣi.
AL-BASIIR: Ẹni tí O ṣe pe O n ri gbogbo nnkan, O si n ri gbogbo nnkan boya o kere ni tabi o tobi.
AL-HALIIM: Oun ni imọ Rẹ kari gbogbo nnkan lori ohun ti o ti lọ tabi ti n ṣẹlẹ lọwọ tabi ti yoo pada ṣẹlẹ lọjọ iwaju.
AR-RAHMAAN: Ẹni tí O ṣe pe ikẹ Rẹ kari gbogbo ẹda Rẹ ati gbogbo nǹkan ti n ṣẹmi, gbogbo ẹrusin ati ẹda ni n bẹ labẹ ikẹ Rẹ.
AR-ROZZAAQ: Ọba ti ijẹẹmu gbogbo ẹda ninu eeyan, alijannu ati gbogbo ẹranko n bẹ ni ọwọ Rẹ.
AL-HAYY: Alaaye ti ko nii ku, gbogbo ẹda ni yoo si ku.
"Ọba Ńlá: Ẹni ti O jẹ pe gbogbo pipe n bẹ fun Un ati gbogbo titobi nibi awọn orukọ Rẹ ati awọn iroyin Rẹ ati awọn iṣẹ Rẹ."