Skip to content

Dárúkọ apa kan awọn orukọ ati awọn iroyin Ọlọhun ti O ga julọ.

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

س32: اذكر بعض أسماء الله تَعَالَى وصفاته.

Ibeere ẹlẹẹkejilelọgbọn: Dárúkọ apa kan awọn orukọ ati awọn iroyin Ọlọhun ti O ga julọ?

الجواب

ج:الله، والرب، والرحمن، والسميع، والبصير، والعليم، والرزاق، والحي، والعظيم، والحكيم .... إلى غير ذلك من الأسماء الحسنى والصفات العلى.

Idahun- Ọlọhun, Ọba Olutọju, Onikẹẹ, Olugbọ, Oluriran, Onimimọ, Olupese, Alaaye, Ọba ti O tobi.... ati bẹẹ bẹẹ lọ ninu awọn orukọ ti o dara julọ ati awọn iroyin ti o ga julọ.