Skip to content

Nibo ni ile awọn alaigbagbọ?

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

Nibo ni ile awọn alaigbagbọ?

س30: ما هي دار الكافرين؟

الجواب

Ina ni, Ọlọhun ti O ga sọ pe:

nítorí náà ẹ ṣọ́ra fún Iná, èyí tí ìkoná rẹ̀ jẹ́ àwọn ènìyàn àti òkúta tí Wọ́n pa lésè sílẹ̀ de àwọn aláìgbàgbọ́. 24

[Suuratul-Baqarah: 24].

ج:النار، قال تَعَالَى:

﴿فَٱتَّقُواْ ٱلنَّارَ ٱلَّتِي وَقُودُهَا ٱلنَّاسُ وَٱلۡحِجَارَةُۖ أُعِدَّتۡ لِلۡكَٰفِرِينَ﴾

[البقرة: 24].