"Ibeere ẹlẹẹkejilelogun: Ki ni ṣọbẹ-ṣelu ati awọn iran rẹ? "
- الموضوعات
- التوحيد وحمايته
- التصنيف الشرعي
- العقيدةالإسلامنواقض الإسلامالنفاق
- الباب / الفصل
- قسم العقيدة
السؤال
"Ibeere ẹlẹẹkejilelogun: Ki ni ṣọbẹ-ṣelu ati awọn iran rẹ? "
س٢٢: ما هو النفاق وأنواعه؟
الجواب
"Idahun- "
"1- Sọbẹ-ṣelu nla: Oun ni fifi aigbagbọ pamọ ati ifi igbagbọ han. "
"Yio maa mu ni kuro ninu Isilaamu, o wa ninu aigbagbọ nla. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:
"{Dájúdájú àwọn ṣọ̀be-ṣèlu mùsùlùmí yóò wà nínú àjà ìsàlẹ̀ pátápátá nínú Iná. O ò sì níí rí alárànṣe kan fún wọn 145}
"[Surah An-Nisâ': 48]"
"2- Sọbẹ-ṣelu (Oju eji) kekere: "
"Gẹgẹ bii: Irọ ati iyapa adehun ati ijanba afọkantan. "
"Ko nii mu ni kuro ninu Isilaamu, o wa ninu awọn ẹṣẹ ati pe ẹni ti o n ṣe e maa lẹ́tọ̀ọ́ si iya. "
"Ojiṣẹ Ọlọhun -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "
Àmì ti a fi n da munafiki mọ mẹta ni: Ti o ba sọrọ yóò parọ, ti o ba ṣe àdéhùn yóò yapa, ti wọn ba fi ọkàn tan an yóò jamba
"Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa. "
ج:1. النفاق الأكبر: وهو إبطان الكفر وإظهار الإيمان.
ويُخرِجُ من الإسلام وهو من الكفر الأكبر.
قال تَعَالَى:
﴿إِنَّ ٱلۡمُنَٰفِقِينَ فِي ٱلدَّرۡكِ ٱلۡأَسۡفَلِ مِنَ ٱلنَّارِ وَلَن تَجِدَ لَهُمۡ نَصِيرًا﴾
[النساء: ١٤٥].
- النفاق الأصغر:
مثل: الكذب، وإخلاف الوعد، وخيانة الأمانة.
ولا يُخرج من الإسلام، وهو من الذنوب، وصاحبه معرَّض للعذاب.
قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:
«آية المنافق ثلاث: إذا حدث كذب، وإذا وعد أخلف، وإذا اؤتمن خان»
رواه البخاري ومسلم.