Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkọkanlelogun: Aigbagbọ a maa jẹ pẹlu ọrọ ati iṣẹ ati adisọkan, mu àpẹrẹ wa fun iyẹn? "

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

"Ibeere ẹlẹẹkọkanlelogun: Aigbagbọ a maa jẹ pẹlu ọrọ ati iṣẹ ati adisọkan, mu àpẹrẹ wa fun iyẹn? "

س٢١: الكفر يكون بالقول والعمل والاعتقاد، مثل لذلك.

الجواب

"Idahun- Àpẹrẹ ọrọ: Bibu Ọlọhun -mimọ ni fun Un- tabi Ojiṣẹ Rẹ -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-."

"Àpẹrẹ iṣẹ: Yiyẹpẹrẹ Kuraani tabi fifi ori kanlẹ fun ẹni ti o yatọ si Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- "

"Àpẹrẹ adisọkan: Didi adisọkan pe nnkankan n bẹ ti o lẹ́tọ̀ọ́ si ijọsin yatọ si Allahu -ti ọla Rẹ ga- tabi pe adẹdaa kan ń bẹ pẹlu Allahu -ti ọla Rẹ ga-. "

ج:مثال القول: سب الله سُبْحَانَهُ أو رسوله صلى الله عليه وسلم.

مثال العمل: إهانة المصحف أو السجود لغير الله تَعَالَى.

مثال الاعتقاد: الاعتقاد أن هناك من يستحق العبادة غير الله تَعَالَى، أو أن هناك خالقًا مع الله تَعَالَى.