Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹtalelogun: Ta ni opin awọn Anabi ati awọn Ojiṣẹ? "

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

"Ibeere ẹlẹẹkẹtalelogun: Ta ni opin awọn Anabi ati awọn Ojiṣẹ? "

س٢٣: من هو خاتم الأنبياء والمرسلين؟

الجواب

"Idahun- oun ni Muhammad (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a). "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{(Ànábì) Muhammad kì í ṣe bàbá ẹnì kan kan nínú àwọn ọkùnrin yín, ṣùgbọ́n (ó jẹ́) Òjíṣẹ́ Allāhu àti òpin àwọn Ànábì...} "

[Surah Al-Ahzâb: 21]"

"- Ojiṣẹ Ọlọhun -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "

«Emi ni opin awọn Anabi, ko si Anabi kankan lẹyin mi» "

"Abu Daud ati Tirmidhi ati ẹni ti o yatọ si wọn ni wọ́n gba a wa. "

ج:هو محمد صلى الله عليه وسلم.

قال تَعَالَى:

﴿مَّا كَانَ مُحَمَّدٌ أَبَآ أَحَدٖ مِّن رِّجَالِكُمۡ وَلَٰكِن رَّسُولَ ٱللَّهِ وَخَاتَمَ ٱلنَّبِيِّـۧنَۗ﴾

[الأحزاب: ٤٠].

وقال رسول الله ﷺ:

«وأنا خاتم النبيين لا نبي بعدي»

رواه أبو داود والترمذي وغيرهما.