Skip to content

السؤال

س45: ما هو فضل الحج؟

Ibeere kẹrinlelogoji: Ki ni ọla ti n bẹ fun Hajj?

الجواب

ج:عن أبي هريرة رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ، قال: سمعت رسول الله ﷺ يقول:

«من حج لله فلم يرفث ولم يفسق؛ رجع كيوم ولدته أمه»

رواه البخاري وغيره.

  • «كيوم ولدته أمه»: أي بغير ذنب.

Idahun- Lati ọdọ Abu Huraira (ki Ọlọhun yọnu si i) o sọ pe:

Ẹni tí o ba ṣe hajj nitori Ọlọhun ti ko ba iyawo rẹ sun oorun ìfẹ́, ti ko si dá ẹ̀ṣẹ̀; yoo pada gẹgẹ bi ọjọ ti iya Rẹ bi i.

Bukhaari ati awọn ẹlomiran ni wọ́n gba a wa.

«Gẹgẹ bii ọjọ ti iya rẹ bi i»: itumọ rẹ ni pe lai ni ẹṣẹ kankan.