Skip to content

السؤال

س42: ما سنن الصيام؟

Ìbéèrè kọkanlelogoji: Ki ni awọn sunnah aawẹ gbigba?

الجواب

ج:١. تعجيل الفطر.

  1. السحور وتأخيره.
  2. الزيادة في أعمال الخير والعبادة.
  3. قول الصائم إذا شتم: إني صائم.
  4. الدعاء عند الفطر.
  5. الفطر على رطب أو تمر، فإن لم يجد؛ فعلى ماء.

Idahun- 1- Yiyara ṣinu

  1. Saari jijẹ ati lilọ ọ lara.
  2. Nini alekun lori awọn iṣẹ rere ati ijọsin.
  3. Ki alaawẹ sọ nigba ti wọn ba bu u pe: Alaawẹ ni mi.
  4. Ṣiṣe adura nigba ti a ba fẹ ṣinu.
  5. Fifi eso dabinu tutu abi gbigbẹ ṣinu, ti ko ba si; ni o too kan omi.