Skip to content

السؤال

Ibeere akọkọ:

Dida ẹjẹ latara oloyun ni ọsan Ramadan, njẹ yoo lapa lara awẹ rẹ?

س14: نزول الدم من الحامل في نهار رمضان، هل يؤثّر على صومها؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Ti ẹjẹ nnkan oṣu ba jade ti obinrin si jẹ alaawẹ, dajudaju awẹ rẹ maa bajẹ; fun ọrọ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pe:

“Ṣe ko kii ṣe pe ti o ba ti ṣe nnkan oṣu ko nii kirun, ko si nii gba awẹ ni?”

Fun idi eyi wọn ka a si ara awọn nnkan ti n ba awẹ jẹ, ati pe ẹjẹ ìbímọ da gẹgẹ bii rẹ, ati pe jidade ẹjẹ nnkan oṣu ati ìbímọ n ba awẹ jẹ

Jijade ẹjẹ latara oloyun ni ọsan awẹ ti o ba jẹ nnkan oṣu da gẹgẹ bii ẹjẹ nnkan oṣu ẹni ti kii ṣe oloyun, o n túmọ̀ si pe: Yoo lapa lara awẹ rẹ, ti ko ba kii ṣe ẹjẹ nnkan oṣu ko nii lapa lara rẹ

Ati pe ẹjẹ nnkan oṣu ti o rọrun ki o waye lati ọdọ oloyun ni ki o jẹ ẹjẹ nnkan oṣu ti o n tẹle ara wọn ti ko da lara rẹ lati igba ti o ti loyun, bi ko ṣe pe o n da lara rẹ ni awọn asiko nǹkan oṣù rẹ, eyi jẹ ẹjẹ nnkan oṣu lori ọrọ ti o tẹsuwọn julọ, awọn idajọ ẹjẹ nǹkan oṣu maa fi ẹsẹ rinlẹ fun un

Ṣugbọn ti o ba ti da lara rẹ, lẹyin naa ti o wa n ri ẹjẹ lẹyin iyẹn, kii ṣe ẹjẹ nnkan oṣu nìyẹn, dajudaju eyi ko nii lapa lara awẹ rẹ; torí pé ko kii ṣe ẹjẹ nnkan oṣu

ﺟ14: إذا خرج دم الحيض والأنثى صائمةٌ فإن صومها يفسد؛ لقول النبيّ ﷺ:

«أَلَيْسَ إِذَا حَاضَتْ لَمْ تُصَلِّ، وَلَمْ تَصُمْ؟» [1]

ولهذا نعدّه من المفطّرات، والنّفاس مثله، وخروج دم الحيض والنّفاس مفسدٌ للصوم.

[3] البخاري، كتاب الصوم، باب الحائض تترك الصوم والصلاة (1951).

ونزول الدم من الحامل في نهار رمضان إذا كان حيضًا فإنه كحيض غير الحامل، أي: يؤثّر على صومها، وإن لم يكن حيضًا فإنه لا يؤثّر.

والحيض الّذي يمكن أن يقع من الحامل هو أن يكون حيضًا مطردًا لم ينقطع عنها منذ حملت، بل كان يأتيها في أوقاتها المعتادة، فهذا حيضٌ على القول الراجح، يثبت له أحكام الحيض.

أما إذا انقطع الدم عنها، ثم صارت بعد ذلك ترى دمًا ليس هو الدم المعتاد، فإن هذا لا يؤثّر على صيامها؛ لأنه ليس بحيضٍ.