Apakan ninu awọn obinrin ti wọn n ba oyun jẹ, iṣesi naa ko le ju: Ninu ki obinrin ba oyun jẹ ṣiwaju ki ọlẹ̀ o to pé ní ẹ̀dá, tabi ki o jẹ pe lẹyin ti o ti pe ni ẹ̀dá, ti ìṣètò si ti hàn nibẹ, ki ni idajọ awẹ rẹ ni ọjọ yẹn ti o ba oyun jẹ nibẹ, ati awẹ ọjọ ti o ri ẹjẹ nibẹ?
السؤال
Ibeere akọkọ:

س13: بعض النّساء اللاتي يجهضن لا يخلو الحال: إمّا أن تجهض المرأة قبل تخلّق الجنين، وإما أن تجهض بعد تخلّقه وظهور التخطيط فيه، فما حكم صيامها ذلك اليوم الذي أجهضت فيه، وصيام الأيام الّتي ترى فيها الدم؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Ti ọlẹ̀ naa ko ba i tii pé ni ẹ̀dá, dajudaju ẹjẹ rẹ ko kii ṣe ẹjẹ ibimọ, lori eyi yoo gba awẹ yoo si kirun, awẹ rẹ si ni alaafia
Ti ọlẹ̀ naa ba ti pé ni ẹ̀dá, dajudaju ẹjẹ naa maa jẹ ẹjẹ ibimọ, ko lẹtọọ fun un lati kirun nibẹ tabi lati gba awẹ
Ofin ti o de ọrọ yii ni pe: Ti ẹ̀dá ọlẹ naa ba ti pe, ẹjẹ naa maa jẹ ẹjẹ ibimọ, ti ko ba tii pé ni ẹ̀dá, dajudaju ẹjẹ rẹ ko kii ṣe ẹjẹ ibimọ, ti ẹjẹ naa ba jẹ ẹjẹ ibimọ, wọn ṣe ni eewọ fun un nnkan ti wọn ṣe ni eewọ fun ẹni ti ẹjẹ ìbímọ n da lara rẹ, ti ko ba kii ṣe ẹjẹ ìbímọ, ìyẹn ko nii jẹ eewọ fun un.
ﺟ13: إذا كان الجنين لم يخلّق فإن دمها هذا ليس دم نفاسٍ، وعلى هذا فإنها تصوم وتصلّي، وصيامها صحيحٌ.
وإذا كان الجنين قد خلّق فإن الدم دم نفاسٍ، لا يحلّ لها أن تصلّي فيه، ولا أن تصوم.
والقاعدة في هذه المسألة أو الضابط فيها: أنه إذا كان الجنين قد خلّق فالدم دم نفاسٍ، وإذا لم يخلق فليس الدم دم نفاسٍ، وإذا كان الدم دم نفاسٍ فإنه يحرم عليها ما يحرم على النّفساء، وإذا كان غير دم النّفاس فإنه لا يحرم عليها ذلك.