Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹrin: Parí hadisi “ẹni ti o pe ju ni ìgbàgbọ́ nínú àwọn mumini…”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ?"

الباب / الفصل
قسم الحديث

السؤال

س4: أكمل حديث «أكمل المؤمنين إيمانًا ...»، واذكر بعض فوائده.

"Ibeere ẹlẹẹkẹrin: Parí hadisi “ẹni ti o pe ju ni ìgbàgbọ́ nínú àwọn mumini…”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ?"

الجواب

ج:عن أبي هريرة رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ قال: قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:

«أكمل المؤمنين إيمانًا: أحسنهم خلقًا»

رواه الترمذي وقال: "حديث حسن صحيح".

فوائد من الحديث:

  1. الحث على حسن الخلق.
  2. وأن كمال الخلق من كمال الإيمان.
  3. وأن الإيمان يزيد وينقص.

"Idahun- lati ọdọ Abu Hurayra- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Ojisẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "

“Ẹni ti o pe julọ ninu awọn mumini ni igbagbọ: Ni ẹni ti o dára julọ ninu wọn ni iwa”.

"Tirmidhi ni o gba a wa, o wa sọ pe: “Hadiisi to daa ni to ni alaafia".

Awọn anfaani inu Hadīth:

"1- Iṣenilojukokoro si iwa dáadáa. "

"2- Dajudaju pipe iwa wa ninu pipe igbagbọ. "

  1. Igbagbọ a maa lekun a si maa dikun. "