Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹfa: Parí Hadiisi: “Ẹnikẹ́ni ninu yin o ni tii di olugbagbọ titi maa fi di ẹni ti o ni ifẹ si julọ....” ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ? "

الباب / الفصل
قسم الحديث

السؤال

س6: أكمل حديث: «لا يؤمن أحدكم حتى أكون أحب إليه ...»، واذكر بعض فوائده.

"Ibeere ẹlẹẹkẹfa: Parí Hadiisi: “Ẹnikẹ́ni ninu yin o ni tii di olugbagbọ titi maa fi di ẹni ti o ni ifẹ si julọ....” ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ? "

الجواب

ج:عن أنس رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ، قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:

«لا يؤمن أحدكم حتى أكون أحب إليه من والده، وولده، والناس أجمعين»

رواه البخاري ومسلم.

من فوائد الحديث:

  • يجب محبة النبي صلى الله عليه وسلم أكثر من كل الناس.
  • أن ذلك من كمال الإيمان.

"Idahun- lati ọdọ Anas- ki Ọlọhun yọnu si i-, Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "

“Ẹnikẹni ninu yin o ni tii di olugbagbọ titi maa fi di ẹni ti o ni ifẹ si ju obi rẹ lọ, ati ọmọ rẹ, ati gbogbo eniyan patapata”.

"Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa. "

"Ninu awọn anfaani to wa ninu Hadiisi naa: "

Nini ifẹ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ju gbogbo eniyan lọ jẹ dandan. "

Ati pe iyẹn wa ninu pipe igbagbọ.