Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkarun-un: Parí hadiisi: “Ẹni ti o ba bura pẹlu nnkan to yatọ si Ọlọhun....”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ?"

الباب / الفصل
قسم الحديث

السؤال

س5: أكمل حديث: «من حلف بغير الله ...»، واذكر بعض فوائده.

"Ibeere ẹlẹẹkarun-un: Parí hadiisi: “Ẹni ti o ba bura pẹlu nnkan to yatọ si Ọlọhun....”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ?"

الجواب

ج:عن ابن عمر رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُما أن النبي ﷺ قال:

«من حلف بغير الله؛ فقد كفر أو أشرك».

رواه الترمذي.

فوائد من الحديث:

  • لا يجوز الحلف إلا بالله تَعَالَى.
  • الحلف بغير الله تَعَالَى من الشرك الأصغر.

"Idahun- lati ọdọ Ibn Umar -ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji- dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "

“Ẹni ti o ba bura pẹlu nnkan to yatọ si Ọlọhun; ti ṣe aigbagbọ tabi da ẹbọ pọ mọ Ọlọhun”."

Tirmidhiy ni o gba a wa

Awọn anfaani inu Hadīth:

"1- Bibura ko tọ afi pẹlu Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- "

"2- Bibura pẹlu nnkan to yatọ si Ọlọhun wa ninu ẹbọ kekere."