"Ibeere ẹlẹẹkọkanlelogoji: Ki ni nǹkan to n jẹ ojúṣe pipaṣe dáadáa ati kíkọ ohun buruku? "
- الباب / الفصل
- قسم العقيدة
السؤال
س41: ما هو واجب الأمر بالمعروف والنهي عن المنكر؟
"Ibeere ẹlẹẹkọkanlelogoji: Ki ni nǹkan to n jẹ ojúṣe pipaṣe dáadáa ati kíkọ ohun buruku? "
الجواب
ج:المعروف: هو الأمر بكل طاعة لله عَزَّ وَجَلَّ،
والمنكر: هو النهي عن كل معصية لله عَزَّ وَجَلَّ.
- قال تَعَالَى:
﴿كُنتُمۡ خَيۡرَ أُمَّةٍ أُخۡرِجَتۡ لِلنَّاسِ تَأۡمُرُونَ بِٱلۡمَعۡرُوفِ وَتَنۡهَوۡنَ عَنِ ٱلۡمُنكَرِ وَتُؤۡمِنُونَ بِٱللَّهِۗ﴾
[آل عمران: ١١٠].
"Idahun- AL’MAHRUUF: Oun ni pipaṣe lati ṣe gbogbo itẹle Ọlọhun- Alagbara ti O gbọnngbọn-, AL-MUNKAR: Oun ni kikọ kuro nibi gbogbo ṣiṣẹ Ọlọhun Alagbara ti O gbọnngbọn.
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:
"{Ẹ jẹ́ ìjọ t’ó lóore jùlọ, tí A gbé dìde fún àwọn ènìyàn; ẹ̀ ń pàṣẹ ohun rere, ẹ̀ ń kọ ohun burúkú, ẹ sì gbàgbọ́ nínú Allāhu }
[Surah Âl-`Imrân: 19]"