Skip to content

"Ibeere ogoji: Ki ni igbarale Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- "

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

س40: ما هو التوكل على الله تَعَالَى؟

"Ibeere ogoji: Ki ni igbarale Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- "

الجواب

ج:هو الاعتماد على الله تَعَالَى في جلب المنافع ودفع المضار، مع الأخذ بالأسباب.

قال تَعَالَى:

﴿وَمَن يَتَوَكَّلۡ عَلَى ٱللَّهِ فَهُوَ حَسۡبُهُۥٓۚ﴾

[الطلاق: 3].

﴿حَسْبُهُ﴾: أي كافيه.

Ìdáhùn- Oun ni igbarale Ọlọhun ti ọla Rẹ ga lati fa àǹfààní wa ati lati ti inira lọ, pẹ̀lú lílo àwọn okùnfà

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Àti pé ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé Allāhu, Ó máa tó o }

"[Surah At-Talâq: 3]"

"{Hasbuhu} : Ìtumọ̀ rẹ ni O maa to fun un. "