Skip to content

السؤال

س1: عرف الطهارة.

"Ibeere kini: Ṣàlàyé imọra?"

الجواب

ج:الطهارة: هي رفع الحدث، وزوال الخبث. أي: رفع ما يمنع من الصلاة.

قال النبي صلى الله عليه وسلم:

«مِفْتَاحُ الصَّلَاةِ الطُّهُورُ»

رواه أبو داود.

طهارة من الخبث: وهي أن يزيل المسلم ما وقع من النجاسة على بدنه، أو على ثوبه، أو على البقعة والمكان الذي يصلي فيه.

طهارة من الحدث: وهي التي تكون بالوضوء أو الغسل، بالماء الطهور، أو التيمم لمن فقد الماء، أو تعذر عليه استعماله.

"Imọra: Oun ni mimu ẹgbin ti n jáde láti ara kúrò, ati kikuro ẹgbin ti o kuro lára bọ́ sára nǹkan mìíràn.

"Mimọ ẹgbin ti a le fi ojú ri: Oun ni ki musulumi mu nnkan ti o wa ni ara rẹ ninu ẹgbin kuro, tabi to wa ni aṣọ rẹ, tabi to wa lori ilẹ ati aye ti o fẹ kirun nibẹ. "

"Mimọ ẹgbin ti a ko le fi ojú ri: Oun maa jẹ pẹlu aluwala tabi iwẹ, pẹlu omi ti o mọ tabi imọra oni erupẹ fun ẹni ti ko ri omi, tabi ti o ṣòro fún un láti lò ó. "