Skip to content

السؤال

س٣: من أين نأخذ الأخلاق؟

"3- Nibo ni a ti maa mu awọn ìwà?"

الجواب

ج:من القرآن الكريم، قال تَعَالَى:

﴿إِنَّ هَذَا الْقُرْآَنَ يَهْدِي لِلَّتِي هِيَ أَقْوَمُ﴾

[الإسراء: ٩].

  • ومن السنة النبوية: حيث قال رسولُ اللهِ ﷺ:

«إنَّما بُعِثْتُ لِأُتَمِّمَ صالحَ الأَخلاقِ»

رواه أحمد.

"Idahun- Ninu Kuraani Alapọn-ọnle, Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Dájúdájú al-Ƙur’ān yìí, ó ń fini mọ̀nà sí ọ̀nà tààrà}"

[Suuratul-Israa: 57].

"Ninu ọrọ ojiṣẹ Ọlọhun: Nibi ti ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ti sọ pe: "

“Dájúdájú wọn gbe mi dide lati pe awọn eyi to daa ninu awọn iwa”.

Ahmad ni o gba a wa "