السؤال
س10: ما آداب المجلس؟
"Ibeere 10: Ki ni awọn ẹkọ ààyè ìjókòó?"
الجواب
ج:1. أسلم على أهل المجلس.
- أجلس حيث ينتهي بي المجلس، لا أقيم أحدًا من مجلسه، أو أجلس بين اثنين إلا بإذنهما.
- أفسح المجلس ليجلس غيري.
- لا أقاطع حديث المجلس.
- أستأذن وأسلم قبل الانصراف من المجلس.
- فعن ابن عمر رضي الله عنهما، عن النبي صلى الله عليه وسلم:
«أنه نهى أن يقام الرجل من مجلسه، ويجلس فيه آخر، ولكن تفسحوا وتوسعوا».
رواه البخاري.
- في الحديث:
«إذا انتهى أحدكم إلى المجلس فليسلم، فإذا أراد أن يقوم فليسلم، فليست الأولى بأحق من الآخرة»
رواه الترمذي وأبو داود.
- عندما ينتهي المجلس أدعو دعاء كفارة المجلس وهو:
«سبحانك اللهم وبحمدك، أشهد أن لا إله إلا أنت، أستغفرك وأتوب إليك».
"Idahun- 1- Maa salamọ si awọn ti wọn wa ni ìjókòó."
"2- Maa jókòó si ibi ti ìjókòó naa ba pari si, mi o si nii gbe ẹnikẹni dide kuro ni ibùjókòó rẹ tabi pe ki n jókòó laarin awọn meji ayaafi pẹlu iyọnda wọn."
"3- Maa gba ẹlomiran láàyè láti jókòó."
"4- Mi o nii ja lu ọrọ ni ìjókòó."
"5- Maa gba iyọnda maa si salamọ ki n to kuro ni ìjókòó."
"6- Nígbà tí ìjókòó ba ti pari, maa ṣe adua kaffāratul Majlis (pipa ẹṣẹ ìjókòó rẹ)"
"«Subhānaka Llāhummọ wabi hamdiKa, ash-hadu an lā ilāha illā Anta, astagfirukKa wa atūbu ilayKa»."