Skip to content

Ki ni awọn sunnah (asegbọrẹ) awọn Irun wakati márùn-ún? Kí sì ni ọla ti n bẹ fun un?

الباب / الفصل
قسم الفقه

السؤال

س28: ما السنن الرواتب؟ وما فضلها؟

Ibeere 27: Ki ni awọn sunnah (asegbọrẹ) awọn Irun wakati márùn-ún? Kí sì ni ọla ti n bẹ fun un?

الجواب

ج:ركعتان قبل الفجر.

  • أربع ركعات قبل الظهر.
  • ركعتان بعد الظهر.
  • ركعتان بعد المغرب.
  • ركعتان بعد العشاء.

فضلها: قال النبي صلي الله عليه وسلم:

«من صلى في اليوم والليلة اثنتي عشرة ركعة تطوعًا بنى الله له بيتًا في الجنة»

رواه مسلم وأحمد وغيرهما.

Idahun- Raka‘a meji ṣíwájú Al-fajri.

Raka‘a mẹẹrin ṣíwájú irun aila.

Raka‘a meji lẹyin irun aila.

Raka‘a meji lẹyin Magrib.

Raka‘a meji lẹyin Ishai.

Ọla rẹ: Anabi sọ pe:

«Ẹniti o ba ki Raka‘a akigbọrẹ mejila ni ojumọ (aarọ ati alẹ) Ọlọhun maa kọ ile kan fun un ninu ọgba alujanna»

Muslim ati Ahmad ati ẹlomiran yatọ si awọn mejeeji ni wọn gba a wa.