Skip to content

السؤال

س30: ما حكم صلاة الجمعة؟

Ibeere 29: Ki ni idajọ Irun Jumu‘a?

الجواب

ج:فرض عين على كل مسلم، ذكر، بالغ، عاقل، مقيم.

قال تَعَالَى:

﴿ يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُوٓاْ إِذَا نُودِيَ لِلصَّلَوٰةِ مِن يَوۡمِ ٱلۡجُمُعَةِ فَٱسۡعَوۡاْ إِلَىٰ ذِكۡرِ ٱللَّهِ وَذَرُواْ ٱلۡبَيۡعَۚ ذَٰلِكُمۡ خَيۡرٞ لَّكُمۡ إِن كُنتُمۡ تَعۡلَمُونَ﴾

[الجمعة: ٩].

Ọran-anyan ojulowo ni i lori gbogbo Musulumi ti o jẹ ọkunrin ti o ti balaga ti o ni laakaye ti o n bẹ ninu ilu (ti kii ṣe arinrin-ajo).

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

﴾Ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, nígbà tí wọ́n bá pe ìrun ní ọjọ́ Jum‘ah, ẹ yára lọ síbi ìrántí Allāhu, kí ẹ sì pa kátà-kárà tì. Ìyẹn lóore jùlọ fun yín tí ẹ bá mọ̀.9﴿

[Sūratul Kāfirūn: 9].