Skip to content

السؤال

س29: ما أفضل أيام الأسبوع؟

Ibeere 28: Ewo lo ni ọla ju ninu awọn ọjọ ọsẹ?

الجواب

ج:يوم الجمعة، قال النبي عَلَيْهِ الصَّلَاةُ وَالسَّلَامُ:

«إن من أفضل أيامكم يوم الجمعة فيه خلق آدم وفيه قبض وفيه النفخة وفيه الصعقة فأكثروا علي من الصلاة فيه فإن صلاتكم معروضة علي».

قالوا يا رسول الله وكيف تعرض صلاتنا عليك وقد أرمت؟ – يقولون بليت – فقال:

«إن الله عَزَّ وَجَلَّ حرم على الأرض أجساد الأنبياء»

رواه أبو داود وغيره.

Idahun- Ọjọ Jumu‘ah, Anabi- ki ikẹ ati ọla maa ba a- sọ pe:

«Dajudaju ninu awọn ọjọ yin to daa julọ ni ọjọ Jumu‘ah, ninu ẹ ni wọn da Ādam, ninu ẹ ni wọn gba ẹmi rẹ, ninu ẹ feere fifun o ti waye, ninu ẹ ni kiku (gbogbo ẹda) o ti waye; nitori naa ẹ pọ ni ṣiṣe assalātu fun mi ninu ẹ; nítorí pé dajudaju wọn yio maa fi assalātu yin han mi»

O sọ pe: Wọn sọ pe irẹ Ojiṣẹ Ọlọhun, bawo ni wọn o ṣe maa fi awọn assalātu wa han ọ ti o si jẹ wipe o ti kẹfun- nnkan ti wọn n sọ ni pe o ti jẹra- o wa sọ pe:

«Dajudaju Ọlọhun - ti O biyi ti O si tun gbọnngbọn - ti ṣe awọn ara awọn Anabi Rẹ ni eewọ fun ilẹ».

Abu Daūd ati ẹlomiran yatọ si i ni wọ́n gba a wa.