Skip to content

Kí ni awọn majẹmu nini alaafia pipa khuffi (abọsẹsẹ alawọ) mejeeji? Idahun–

الباب / الفصل
قسم الفقه

السؤال

س١٣: ما هي شروط صحة المسح على الخفين؟

Ibeere 13– Kí ni awọn majẹmu nini alaafia pipa khuffi (abọsẹsẹ alawọ) mejeeji? Idahun–

الجواب

ج:١. أن يلبس الخفين على طهارة، أي بعد وضوء.

لحديث المغيرة رضي الله عنه قال: كنت مع النبي صلى الله عليه وسلم في سفر، فأهويت لأنزع خفيه، فقال:

«دعهما فإني أدخلتهما طاهرتين». فمسح عليهما.

متفق عليه.

  1. أن يكون الخف طاهرًا، فلا يجوز المسح على النجس.
  2. أن يكون الخف ساترًا للمحل المفروض غسله في الوضوء.
  3. أن يكون المسح خلال المدة المحددة، للمقيم غير المسافر: يوم وليلة، وللمسافر: ثلاثة أيام ولياليهن.

لحديث علي رضي الله عنه:

جعل رسول الله صلى الله عليه وسلم ثلاثة أيام ولياليهن للمسافر، ويومًا وليلة للمقيم.

رواه مسلم.

  1. ki o wọ abọsẹsẹ alawọ mejeeji lori imọra, itumọ rẹ ni lẹyin aluwala.
  2. Ki abọsẹsẹ alawọ o jẹ nǹkan ti o mọ; nitori naa ko lẹ́tọ̀ọ́ ki o pa a lori ẹgbin.
  3. Ki abọsẹsẹ alawọ jẹ nnkan ti o bo aaye ti fifọ rẹ jẹ dandan nibi aluwala.
  4. Ki pipa naa o jẹ laaarin asiko ti a ti fi gbedeke sí, fun ẹni ti o wa ni ile ti kii ṣe arinrin-ajo: Ọjọ kan ati oru kan, fun arìnrìn-àjò: Ọjọ mẹta pẹlu àwọn oru wọn.