Skip to content

Ki ni nnkan ti o maa n ba pipa abọsẹsẹ alawọ mejeeji jẹ?

الباب / الفصل
قسم الفقه

السؤال

س١٥: ما الذي ينقض المسح على الخفين؟

Ibeere 15- Ki ni nnkan ti o maa n ba pipa abọsẹsẹ alawọ mejeeji jẹ?

الجواب

ج:١. انقضاء مدة المسح، فلا يجوز المسح على الخفين بعد انقضاء مدة المسح المحددة شرعًا، يوم وليلة للمقيم وثلاثة أيام بلياليها للمسافر.

  1. خلع الخفين فإذا نزع الإنسان الخفين أو أحدهما بعد مسحه بطل المسح عليهما.

Idahun-1- Pipari asiko pipa, nitori naa pipa abọsẹsẹ alawọ mejeeji o lẹ́tọ̀ọ́ lẹyin pipari asiko pipa tí a ti paala rẹ ninu sheriah (ofin ẹsin), ọjọ kan ati oru kan fun ẹni ti n bẹ nile, ati ọjọ mẹta pẹlu awọn oru wọn fun arìnrìn-àjò.

  1. Bibọ abọsẹsẹ alawọ mejeeji, ti ọmọnìyàn ba ti le bọ́ abọsẹsẹ alawọ mejeeji tabi ọkan ninu wọn lẹyin ti o ti pa a, pipa mejeeji ti bajẹ.