"Ibeere ẹlẹẹkẹrinlelọgbọn: Ki ni ojuṣe wa si awọn onimimọ musulumi? "
- الموضوعات
- الولاء والبراء وحقوق المسلمينالآداب
- التصنيف الشرعي
- الفضائل والآدابالآداب الشرعيةآداب العالم والمتعلم
- الباب / الفصل
- قسم العقيدة
السؤال
س٣٤: ما واجبنا تجاه علماء المسلمين؟
"Ibeere ẹlẹẹkẹrinlelọgbọn: Ki ni ojuṣe wa si awọn onimimọ musulumi? "
الجواب
ج:نحبهم، ونرجع إليهم في المسائل والنوازل الشرعية، ولا نذكرهم إلا بالجميل، ومن ذكرهم بغير ذلك من السوء؛ فهو على غير السبيل.
- قال تَعَالَى:
﴿يَرۡفَعِ ٱللَّهُ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ مِنكُمۡ وَٱلَّذِينَ أُوتُواْ ٱلۡعِلۡمَ دَرَجَٰتٖۚ وَٱللَّهُ بِمَا تَعۡمَلُونَ خَبِيرٞ﴾
[المجادلة: ١١].
"Idahun- a maa nífẹ̀ẹ́ wọn, a maa ṣẹri pada si ọdọ wọn nipa awọn àlámọ̀rí ati awọn iṣẹlẹ tuntun ti sharia, ki a ma darukọ wọn afi pẹlu daada, ẹnikẹ́ni ti o ba darukọ wọn pẹlu nnkan miiran to yatọ si iyẹn ninu aburu; ko si ni oju-ọna. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:
{Allāhu yóò ṣàgbéga àwọn ipò fún àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo àti àwọn tí A fún ní ìmọ̀ nínú yín. Allāhu sì ni Alámọ̀tán nípa ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́ 11}
[Suuratul-Mujadila 11].