Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkọkandinlọgbọn: Ki ni ile awọn onigbagbọ?"

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

"Ibeere ẹlẹẹkọkandinlọgbọn: Ki ni ile awọn onigbagbọ?"

س29: ما هي دار المؤمنين؟

الجواب

"Idahun- alujanna (ọgba idẹra)" Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Dájúdájú Allāhu yóò mú àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe àwọn iṣẹ́ rere wọ inú Ọgbà Ìdẹ̀ra tí àwọn odò ń ṣàn ní ìsàlẹ̀ rẹ̀...}

"[Suuratu Muhammad: 19]"

ج:الجنة، قال تَعَالَى:

﴿إِنَّ اللَّهَ يُدْخِلُ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِنْ تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ﴾

[محمد: 12].