Ki ni iwọ awọn ara ile Anabi -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ti o jẹ dandan fun wa?
- الموضوعات
- حقوق النبي وأصحابهأهل البيت
- التصنيف الشرعي
- العقيدةأهل البيت وفضلهم
- الباب / الفصل
- قسم العقيدة
السؤال
"Ibeere ẹlẹẹkẹtadinlọgbọn: Ki ni iwọ awọn ara ile Anabi -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ti o jẹ dandan fun wa?"
س27: ما هو حق آل بيت النبي صلى الله عليه وسلم علينا؟
الجواب
"Idahun- A maa nífẹ̀ẹ́ wọn, a si maa mu wọn ni ọrẹ, a si maa korira ẹni ti o ba korira wọn, a o si nii kọja aala nipa wọn, awọn ni awọn iyawo rẹ ati awọn arọmọdọmọ rẹ, ati awọn ọmọ Hashim ati awọn ọmọ Muttolib ninu awọn onigbagbọ. "
ج:نحبهم ونتولاهم ونبغض من يبغضهم ولا نغلو فيهم، وهم أزواجه، وذريته، وبنو هاشم، وبنو المطلب من المؤمنين.
قال تعالى:
﴿إِنَّمَا يُرِيدُ ٱللَّهُ لِيُذۡهِبَ عَنكُمُ ٱلرِّجۡسَ أَهۡلَ ٱلۡبَيۡتِ وَيُطَهِّرَكُمۡ تَطۡهِيرٗا﴾
[الأحزاب: ٣٣].
وفي الحديث عن النبي صلى الله عليه وسلم قال:
«أذكركم الله في أهل بيتي، أذكركم الله في أهل بيتي، أذكركم الله في أهل بيتي»
رواه مسلم.