Skip to content
رسول الإسلام محمد صلى الله عليه وسلم

رسول الإسلام محمد صلى الله عليه وسلم

Mo bẹrẹ pẹlu orúkọ Ọlọhun Ọba Ajọkẹ-ayé Aṣakẹ-ọrun Òjíṣẹ́ awọn mùsùlùmí anọbi Muhammad (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa ba a) Ọrọ ni ṣókí nípa ojiṣẹ ìsìláàmù, Muhammad - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa ba a- màá ṣàlàyé orúkọ rẹ, ati iran rẹ ati ìlú rẹ, àti ìgbéyàwó rẹ, àti iṣẹ rírán rẹ, àti ohun tí o pepe si, ati awọn àmì ijẹ anabi rẹ, àti òfin rẹ, àti ihà tí àwọn ọ̀tá rẹ kọ si i. (1) mo n ṣe ojukokoro lórí ki n ṣe ifi we ara wọn láàárín ọrọ meji ojiṣẹ Muhammad lati ṣe akiyesi fun ongbifọ ki wọn si ṣe akiyesi ìyẹn 1- Orúkọ rẹ, ati ìran rẹ, àti ilu ti wọn ti bí i tí o sì dàgbà si. Ojiṣẹ awọn mùsùlùmí naa…

Èdè: lang_yo
Ẹni tí ó pèsè:
Ẹ̀yà: 1.2

These files are generated automatically from the book's text; their layout may differ from the printed edition.

0%
Font size