Skip to content

السؤال

س٢١: ماذا تقول قبل أكل الطعام؟

"Ibeere 21: Ki ni waa sọ ṣíwájú jijẹ ounjẹ?"

الجواب

ج:«بسم الله».

فإذا نسيت في أوله فقل:

«بسم الله في أوله وآخره»

رواه أبو داود والترمذي.

"Idahun- «BismiLlāhi» "

"Ti o ba gbagbe lati wi i ni ibẹrẹ rẹ, ki o sọ pe:"

"BismiLlāhi fii awwalihii wa aakhirihii» "

"Abu Daud ati Tirmidhi ni wọ́n gba a wa. "