Skip to content

السؤال

س15: ما أول ما نزل عليه من القرآن؟

Ibeere 15: Kí ni akọkọ nnkan ti Ọlọhun sọkalẹ fun un ninu Al-Qur'āni?

الجواب

ج:قوله تَعَالَى:

﴿ٱقۡرَأۡ بِٱسۡمِ رَبِّكَ ٱلَّذِي خَلَقَ ١

خَلَقَ ٱلۡإِنسَٰنَ مِنۡ عَلَقٍ 2

ٱقۡرَأۡ وَرَبُّكَ ٱلۡأَكۡرَمُ ٣

ٱلَّذِي عَلَّمَ بِٱلۡقَلَمِ ٤

عَلَّمَ ٱلۡإِنسَٰنَ مَا لَمۡ يَعۡلَمۡ 5﴾

[العلق: 1-5].

Idahun- Gbolohun Ọba- ti ọla Rẹ ga- pe:

Ké (al-Ƙur’ān) pẹ̀lú orúkọ Olúwa rẹ, Ẹni tí Ó dá ẹ̀dá. 1

Ó ṣẹ̀dá ènìyàn láti ara ẹ̀jẹ̀ dídì. 2

Ké e. Olúwa rẹ ni Alápọ̀n-ọ́nlé jùlọ. 3

Ẹni tí Ó fi ìmọ̀ nípa gègé ìkọ̀wé mọ ènìyàn. 4

Ó fi ìmọ̀ tí ènìyàn kò mọ̀ mọ̀ ọ́n. 5

[Suuratul Alaq: 1 - 5]